Just another Lagos Television Editions site

Content on this page requires a newer version of Adobe Flash Player.

Get Adobe Flash player


DOWNLOAD LTV MOBILE
iPHONE, BLACKBERRY, ANDROID and NOKIA

TAKE LTV WITH YOU
You can now have LTV Schedules, News Updates and uReport on the go with our mobile app for your phone. Click on here get for your phone

Also Follow us on social networks
Nipa Mo gbejo mide
Mo gbejo mide je eto ti Gomina Ipinle Eko, Gomina Babatunde Raji Fashola da sile ni nkan bi odun meji sehin, lati ma paari aawo ti o jo mo Oro Ile, Ile, Ogun, igbeyawo, Oowo, Ise ati beebeelo ni Ipinle Eko.
Awon Amoye Mefa ni o ndari eto yi, ninu won lari Amofin, Alufa Ijo, ati omowe. Awon Amoye yi ni o ngbo ejo lenu awon ti o ba mu esun wa, nipa be won yio sipe awon ti a ba mu esu won wa ki won farahan ni Ile ise Tilefison Ilu-eko ni ojo kan ti a ya si oto, ni ojo yi;
Eniti O mu esu wa ati eniti a mu esun re wa yio fi oju kan ara won, olukuluku yio si ro ejo tire, awoye yi yio si da ejo na fun won.

IGBA: Gbogbo Ojo Aiku, Agogo marun si mefa.

E le fi iwe ranse lori:

[email protected]