Agbeyewo Ise Gomina Ambode Ni Odun 2016 Videos LTV 03/01/2017 0 Irinse fun awon olopa, atunse awon opopona to ti baje, ina fun awon opopona ilu eko…eleyi pelu awon nnkan miran ni awon ti gomina Akinwunmi Ambode se ni odun 2016